Ara ire ni ko fi mi da shola allyson lyrics

Get lyrics of Ara ire ni ko fi mi da shola allyson song you love. List contains Ara ire ni ko fi mi da shola allyson song lyrics of older one songs and hot new releases. Get known every word of your favorite song or start your own karaoke party tonight :-).


Sola Allyson Obaniyi - Obirin Lyrics
obinrin ni mi, mo pe lola obinrin ni mi, ma rin ma soge marin gere bi eleni gere, ma tun sapa genge emi ni oluranwo oko emi ni emi ni eni angeli omo eledumare lo mo mi emi ni iya ti o wa eke mi mo fi gbogbo ara sewa eleda mo dupe ko si asise ninu eda mi e bami yo.
Sola Allyson Obaniyi - Adura Ololufe Lyrics
Adura mogba fun e ololufe mi Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi Oo ni kagbako l'aye oo ni r'ogun akoba Oo ni s'irin l'aye be oo ni t'oju ile mole Ainif'okanbale o ni y'odo re lailailailailai Oo ni m'osi l'aye, aye re a ma dara si Ife eledumare ree e ooo ore mi O fewa fun re, o fewa f'ayo taa ba barawa s'otito Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s'ise Iranse alaanu re wa pelu t ...
Sola Allyson Obaniyi - Temisan Lyrics
Motenu more o mo ri mu, te mi san si re o temi (ma) san o REPEAT 1.Ile aye yi o kun fun ja, jeje mode mo de ba ja Wen wen mo ke ija mo ba; abi ki lomo se t'o firi ja Atiwa ateyin ko rorun rara; ohun to fi ya je ni lo pon ni loju, iya o ye ye kómo je lógbomo sanle Mo mona mi pon mo rin titi ti ase oba ok emo ohun ma a da, lófi mu mi rinna ti mo gba debi, eni to nigba lóseto aye mi mo rin ...
Sola Allyson Obaniyi - Iwo Lo Ye Lyrics
Hallelujah Ogo ni fun Baba A fijo filu yin Olorun wa Alaaye ni yoo yin O bo ti ye Hallelujah Ogo Oluwa ooo Eh eh Oluwa ooo Eh eh Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa eeeh Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa Ope ye O ooo eh Ope Eni to joko lori ite ogo fooko ...
Sola Allyson Obaniyi - Olorun Awon Omo Ogun Master Lyrics ...
Lyrics for Olorun Awon Omo Ogun Master by Sola Allyson Obaniyi. Ògo ìyìn ọlá Lóye Ọlọ́run Ọlọ́run àwọn ọmọ Ógùn Ọlọ́run àwọn ọmọ ogún Ògo Ìyìn ọlá Lóye Ọ...
Found 5 lyrics.

Recent lyrics

khaani
ge mig
jidete
fazos
ndiya