Olorun ni o maje by tope alabi lyrics

Get lyrics of Olorun ni o maje by tope alabi song you love. List contains Olorun ni o maje by tope alabi song lyrics of older one songs and hot new releases. Get known every word of your favorite song or start your own karaoke party tonight :-).


Get hot Olorun Ni O Maje By Tope Alabi lyrics at Lyrics.camp!
Tope Alabi - Olorun Ni Yio Ma Je Lyrics
Titi Aye) Alagbara ni ko se segun o Ipa nla ni ko de le ku ooo Aileyipada to la ye ni ikawo Emi se'ba oluda orun o (Emi se'ba oluda orun) Olorun ni yio ma je (akoko nda olu nda aye) Olorun ni yio ma je (patapata pira ogo nibi to pari si) Lana loni lola o (patapata ola) Titi de ayeraye Olorun ni yio maje Ailetuwa o ti wa ko to da orun Tale ri ni ...
Tope Alabi - Oruko Oluwa Lyrics
Ona Re ma pe mi o, arinye ni o eeee (titobi Oga nla) Alade Ogo, iba Re o Olorun to dara, iwa Re wu mi o e Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba Alade Ogo, iba Re o Olorun to dara, iwa Re wu mi o e Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba Awon t'orun n f'ogo fun Un, Elemi eda O na'wo Re lat'orun ja aye o O n rin lori igbi okun Oruko Re nikan lo ko aje ya Agbara Re nikan ni ko le ...
Tope Alabi - Yes and Amen translation in English
English translation of lyrics for Yes and Amen by Tope Alabi. Amin Ase ida a lamo o Eni ti o ni a padanu Iba o to to olu Imo o Eni ti o ni o, ko ni nkan...
Tope Alabi - Oba Aseda Lyrics
A toto n to Olodumare, Olorun ogo, Iba Re, Iba o, Akoda aye, Iwo nikan lo to, iba! A de'da, a m'eda Oba Alamo to mo 'ponri eda o Akoko orun on aye Opo kan a gbamu aye o Ogo ni mo wa yin o o Oba Kabiyesi Re, Olorun toto Ogo, yeeee, ogo Akoko ade Iwo loba Omimi aye ti o le mi lailai o Olu inu awon orun Asaya apesin asako Iwo to tobi ju o lorun O f'aye s'apoti itise lasan Ogo, yeeee, ogo Ogo ye o ...
Tope Alabi - Halleluyah Lyrics
Lyrics for Halleluyah by Tope Alabi. Hallelujah ni won ma ko Hallelujah si wo olurun mi Orin hallelujah ni woo bawon torun ko o... Type song title, artist or lyrics. ... Olorun Ni Yio Ma Je. 04. Ta Lo Dabii Re. 05. Yes and Amen. 06. Iyin Ye O. See more. Exclusive offer. Get up to 3 months of free music.
Tope Alabi - Iyin Ye O Lyrics
Oba to femi Kabiesi re o Iyin ye o Oba to femi Ogo ye o Kabiesi re o eh Ogba mi lowo iku Ore mi otito Ofi keke ogun aye mi jona Olu gbe ja mi ni Ko se ni to le se o; afi wo Kabiesi re o eh Mo juba mo fori ba le fo ba Iwo ni ologo julo Back to chorus O fo gbogbo ilekun ide aba wole si ogo mi Ojo gbogbo jankari wo Emi odi won teriba Okuta ti awon mole ko Wadi pataki igun aye Owo anu re to fi gba ...
Tope Alabi - Mimo L'Oluwa Lyrics
Mi o je foju di o Oba ti o se wo loju wo O ti e leti, ai le dibaje ni o Baba NLA Ku Baba mi O le pin yikin Mimo Gbogbo eni to be mi riri Oluwa, e Teri ba Ewa riri fun Oba tite re ki si Ibere at opin, Olorun ajanaku, tin mi gbo kijikiji Mimo Tabubu, tale bu tan, pupo si ni gbogbo ojo Eje ka sale fun Oba rere ta ba mo riri Emi inu awon woli ...
Found 7 lyrics.

Recent lyrics

sbahle


Close Ad