Oluwa dara lyrics

Get lyrics of Oluwa dara song you love. List contains Oluwa dara song lyrics of older one songs and hot new releases. Get known every word of your favorite song or start your own karaoke party tonight :-).


Get hot Oluwa Dara lyrics at Lyrics.camp!
Bukola Anney feat. Esther Adegbayo - Yoruba Praise and ...
Mo gbagbo pe yo dara fun mi, Mo ni gbagbo ninu Oluwa maa se rere, Po'ojo ola mi yoo dara, Mo mope ohun gbogbo yo dara fun mi. Mo gbagbo pe yo dara fun mi, Mo ni gbagbo ninu Oluwa maa se rere, Po'ojo ola mi yoo dara, Mo mope ohun gbogbo yo dara fun mi. Oluwa ran mi nise, Alleluuya, Emi yo jise naa fun oo.
Tope Alabi - Oruko Oluwa Lyrics
Edit lyrics. Lyrics for Oruko Oluwa by Tope Alabi. Maa yin O, Olorun t'O dara, t'O n s'ohun gbogbo fun mi o Emi o yin O, imole to n f'ona han mi oo e Ore Re koja siso, o kamomo eee. Ona Re ma pe mi o, arinye ni o eeee (titobi Oga nla) Alade Ogo, iba Re o Olorun to dara, iwa Re wu mi o e Mo wa, mi o ri oba to dabi Re ninu gbogbo oba Alade Ogo ...
King Muzet - Gbadurami Lyrics
I want to buy tge bently baba gbo adura mi Eni shishe lonje re dankun bless my hustle Jeki koredele oluwa bless my way Jiji timo ji baba gbo adura mi Kaye mi Dara ...
Tope Alabi - Odara Ni Ife Lyrics
The Lyrics for Odara Ni Ife by Tope Alabi have been translated into 1 languages. E fi'ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye K'orin tuntun s'Oluwa iwo okan mi E ma yo n'nu Oluwa eyin olododo Nitori iyin ye fun Oluwa E fi duru yin Oluwa t'ohun t'eelo orin K'orin naa s'oke kikan k'aye ko gbo o ...
SAMMIE OKPOSO FEAT. KIKE MUDIAGA - OLUWA E TOBI LYRICS
Oluwa e to bi, e to bi o, e to bi (God you are great, you are great) Ko se ni ta le fi sakawe re o, E tobi (None can compare with you, you are great) E to bi, oluwa.(You are great, God) Alagbada Ina (He that covers himself with fire) Oba Iyanu (God of miracles/wonders) Eledumare(The Almighty) Aterere kari aye (The one who spreads over all the ...
Sola Allyson Obaniyi - Ope Lyrics
Lyrics Ope. Ope. Nipa ipa ko, kii s'agbara l'oro se ri b'o se ri B'o ti wu ko ri Oluwa s'olododo f'awon to gba A gbo Oye aye o ye ni to sugbon o da wa loju Alaanu l'Olorun wa. A gbe ni leke, Oluke ni, Oluyan ni sola Aseyiowu O se o Baba t'o fi wa dara iyanu (Iba Iba Iba) Iba o Iba f'Olorun Eledumare to l'ogo oooo (iba) Iba Iba Iba naa ni o (Iba ...
Midnight Crew - Mo Dibo Lyrics
Eyi ni eri ife Oluwa si mi Mo gbe'gbese pataki mo se'gbeyawo Laipe ojo mo ye mo feraku A o ba ti gbemigbin, Oluwa o je Hallelujah ogo ni fun Baba Ma fijo ilu yin Olorun wa Alaaye ni yoo yin o b'o ti ye Hallelujah f'Oba Onibuore Mo dibo fun Jesu Mo dibo fun Jesu Jesu gba akoso Aye mi dara o Mo dibo fun Jesu Jesu gba akoso Aye mi dara o Mo dibo fun Jesu Let me tell you whom we're dancing for ...
Sola Allyson Obaniyi - Adura Ololufe Lyrics
Adura mogba fun e ololufe mi Ire ni mo n su fun e ayanfe oko mi ore mi Oo ni kagbako l'aye oo ni r'ogun akoba Oo ni s'irin l'aye be oo ni t'oju ile mole Ainif'okanbale o ni y'odo re lailailailailai Oo ni m'osi l'aye, aye re a ma dara si Ife eledumare ree e ooo ore mi O fewa fun re, o fewa f'ayo taa ba barawa s'otito Angeli alayo mi faramo tire nse ni won njo s'ise Iranse alaanu re wa pelu t ...
Tope Alabi - Oluwa Otobi Lyrics
The Lyrics for Oluwa Otobi by Tope Alabi have been translated into 1 languages. Oluwa o tobi o tobi o, o tobi ×2 kos'eni tale fi s'afiwe re o o tobi o, ko s'eda tale fi s'akawe re o o tobi o oluwa ×2 O tobi o, oluwa giga lorile ede gbogb gbigbega ni o pupopupo ni o o koja omi okun at'osa o ga po ajulo ose julo Oba Lori aye o tobi o eh agbani ...
Temmie Ovwasa - Afefe Lyrics
Dakun gbe wa sodo mi o. Dakun o Afefe anu Dakun fe wa so do mi o Mase fi mii si le lo. Dakun o Gbogbo anu taye ti gba lowo mi o Dakun gbe pada wale. jowo o Ota ti she tire. aye ti gbo ogun o Sugbo mo ni gbagbo pe oluwa ko kin su o Tori timba lo loni awon araye a ke abimi Leyin osu meta oti tan. wan ti gbagbe mi Mowa gbadura o. jeki aye mi dara o Afefe ire.
Tope Alabi - Fimi Dara Ire Lyrics
Ofi dara ti o daa oo Nebuchadnezari gberaga Ofi dara ti o wun oo Olorun Ara S'aye mi ni re Fimi dara to da Baba oo Olorun Ara Oni'nu Ara Fimi dara to wunmi ooo Olorun Ara S'aye mi logo Fimi dara to da Baba oo Olorun Ara Oni'nu Ara Fimi dara to wunmi ooo S'anu aye mi o Baba Eni To ba fi dara ire Kii fara sinu ku Jekara ayemi kowu egbe mi o Alara ...
Tope Alabi - Oruko Tuntun Lyrics
The Lyrics for Oruko Tuntun by Tope Alabi have been translated into 1 languages. Olorun to da mi w'aye o, lo ni oruko mi amutorunwa Eleda to da mi leniyan lo so mi loruko akoko Emi lologo alayanmo ire, mo w'aye wa f'ogo Olorun han. Aisiki ire, sabaabi idunnu lemi eniyan Olorun to da mi w'aye o, lo ni oruko mi amutorunwa Eleda to da mi leniyan ...
Gaise - Womina Lyrics
Womina, womina, womina, womina Mo ni ko womina, womina, womina, wonima Bi mo se n f'egbe yin baba Pressures everywhere. People morale dey fall But earphones dey my ears I've got no worries at all I dey hear grace for one, mercy dey the other The battle has been won, me I no dey bother Ma lo ro o, eniyan ko, Oluwa lo bami se So therefore I dey rejoice everyday Everything I need now, I got it ...
Mike Abdul feat. Monique - Morire Lyrics
Lyrics for Morire by Mike Abdul feat. Monique. Mo rire, mo rire, mo rire gba o O semi l′oore Mo rire gba o Mo rire, mo rire, mo r'aanu gb...
Tope Alabi - Ibinu Sinmi Laya Were Lyrics
(beeni) Ibinu simi laya were (boo tiri niyen o) O se kondo (ooo) O se kumo kan (ibinu) Ebo ti kale s'orita f'Esu (ko dara laya eniyan) Ase nla be sile nile iku (ooo) Ilekun si o o, fun jamba (A maa faniya pere pere) E wose Satani eeni eko Ibinu simi laye were Beeni Bibeli mi wi fun mi Oko to nbimu lu 'yawo e se lese e Iyawo to nbinu ba nkan ini ...
Pastor J. A. Adelakun - Amona Tete Mabo Lyrics
The Lyrics for Amona Tete Mabo by Pastor J. A. Adelakun have been translated into 1 languages. Amona o Amona tete wa o, amona tete bo Amona tete wa o, amona tete bo (Tori pe) Aye n ba je o, amona tete bo Aye n daru o, amona tete bo Jesu Kiristi l′amona Oun lo le tun le aye wa se A n reti re o Baba, a fe r'oju re Igba ti Jesu ba de, l′aye yi ...
MIKE ABDUL - INTENTIONAL FUJI LYRICS
P'Oluwa fe s'ogo laye mi. Imole to tan yi ire l'obi. Double-Double no more trouble, This i know. Double-Double no more trouble, This i know. P'Oluwa bless me, it's inTenTional. P'aye mi dara, it's inTenTional. Pe mo s'orire, it's inTenTional. Asotele yen ti s'ele, it's inTenTional. E o ribi oti s'ele, it's inTenTional.
Temmie Ovwasa - Afefe translation in English
Translation in English. Afefe ire dakun fe wa si odo mi o. (The breeze of goodness please blow to my location) Bami gbe ire wale jowo o. Please bring goodness home for me. Gbogbo ire taye ti gbalowo mi. (All the good things people have hijacked from me)
Tope Alabi - Oro Kan Soso Lyrics
If you found mistakes, please help us by correcting them. Edit lyrics. The Lyrics for Oro Kan Soso by Tope Alabi have been translated into 1 languages. Oro kan soso Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o. Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Beeni mo wi Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Ohun ti a ...
MIKE ABDUL FEAT. MONIQUE - MORIRE LYRICS
Atubotan mi dara ju, ise Oluwa ni eh eh I lift my head up high in glory You never let me bow in shame Eyi le se fun mi o, Olorun mi (olorun mi) Kini ma fi san ore Re Baba mimo ye eh Mo rire, mo rire, mo rire gba o O semi lore Mo rire gba o Mo rire, mo rire mo r'aanu gba o O semi lore
Chief Commander Ebenezer Obey - Ota Mi Dehin Lyrics ...
Dehin leyin mi Oso Ile o Dehin Lehin mi Aba Teni je o Dehin Lehin mi Elero buburu o Dehin Lehin mi Abinu Eni o Dehin Lehin Mi Oni wa buburu Dehin Lehin mi Repeat x2 Bi ewure ba boju wehin Afi Epe fun elepe Ba aguntan Ba boju wehin Afi Epe fun elepe Aba Teni je Dehin Lehin mi Aiye toto Aiye to to mojuba Mojuba omo araiye Tonba Dan fun e Wa ma pe e ni Okunrin atata, omo jaiye jaiye Toba ti lowo ...
Chief Commander Ebenezer Obey - Anjade Loni Eledumare ...
Lyrics for Anjade Loni Eledumare by Chief Commander Ebenezer Obey. Anjade Lo Loni elwdumare Anjade Lo Loni elwdumare Anjade Lo Loni elwdumare Jijade wa ka ma pade agbako Ohun ti a oje LA n WA Lo baba Ka MA pade Ohun to oje WA. Eni olorun la, Lole LA aye ja Nitori re ni mo se ro mo o Agbokanle MI maje ko dofo o Baba mo gbokan Le o.
Found 22 lyrics.

Recent lyrics

husler
2055