Oluwa mi yio dide song lyrics lyrics

Get lyrics of Oluwa mi yio dide song lyrics song you love. List contains Oluwa mi yio dide song lyrics song lyrics of older one songs and hot new releases. Get known every word of your favorite song or start your own karaoke party tonight :-).


Get hot Oluwa Mi Yio Dide Song Lyrics lyrics at Lyrics.camp!
Lyrics Emi O Kokiki Re Oluwa - Musixmatch - Song Lyrics ...
Emi yio k'okiki re Oluwa Iwo ni o da mi nide Iwo ni koje ki ota yomi Ogo ni f'oruko re Iyin ola, ogo ni fun o Agbara ati'pa je tire Egberun ahonko to yin o A wole a juba re. Oluwa mi emu kigbe pe o Iwo si my mi larada O yo okan mi kuro ninu 'sa oku O si pami mo laaye Korin s'oluwa eyin serafu Kesi dupe 'wa mimo re Ibinu re kiipe ju seju kan Iye ...
King Sunny Ade - Oluwa Lo Yan Mi Wa Lyrics
Eda mi gbe temi komi maa jen si won waye. Ori mi maa jen si won waye lasan lasan. Eda mi ma jen se akoba fun egbe mi. Kira kita ko ran, giri ko ran o. Orilo pin ola koni, ori lon pin ola koni. Eda mi gbe temi komi maa jen si won waye. Emi ti gbo ohun oluwa to wipe wa wa arakunrin O, dide ninu ogba ajara oluwa e kosi maa korin. Wa wa arakunrin o ...
Sola Allyson Obaniyi - Ase Lyrics
Yio da Ta'leni na ti'nsope aye mi o le dide mo? Ta'leni na ti'nsope o ti tan oh oh ah ah! wo mi k'ori p'Oluwa ma dun gan o si po o Ení maa rí akan ko se'ju, a maa gbeti'do ni Inunibini enikan o le pe k'ojo ma la o! Oorun a wo b'otiwu k'eletanu f'apajanu.
Sola Allyson Obaniyi - Ope Lyrics
Type song title, artist or lyrics. Top lyrics ... o mo se 'ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Kabiyesi o Kabiyesi o mo se 'ba Re Oba to ju gbogbo oba lo Aigbagbo bila temi l'Oluwa Oun yoo si dide fun igbala mi Ki n sa ma gb'adura Oun o se 'ranwo 'Gba Krist' wa l'odo mi ifoya ko si B'ona mi ba su, Oun lo sa n to mi Ki n sa gboran sa Oun o si pese B ...
Olubukunola Bekes - Iranlowo (My Help) Lyrics
Iranlowo Mi o todo oluwa wa ti o da orun oun aye Iranlowo Mi latodo re ni oba to da orun aye ranmilowo oluwa, ranmilowo oun ki yio je ki ese mi koye eniti n pamimo kiitogbe beeni kii sun rara oo e no de sleep huuuuuu Iranlowo mi latodo re ni, oba to da orun aye, ranmilowo oluwa ranmilowo ranmilowo 4x
Lyrics Yoruba Praise and Worship… - Song Lyrics and ...
Ti Oluwa ni ile ati ekun re, aye ati awon ti otedo sinu re, nitoripe, oti fi ile sole sori okun, ati sori isan omi. e gbe ori yin soke, eyin enu ona, ki asi gbeyin soke, eyin ilekun ayeraye, ilekun ayeraye, ilekun ayeraye. koba ogo, koba ogo, Oluwa ti ole, Oluwa to ni agbara, ologo didan, eleru niyin, apa nla to so ile aye ro, ko ni nira fun mi ...
Sola Allyson - Ebe Lyrics
Type song title, artist or lyrics. Top lyrics Community Contribute Business. ... mo wa sibi ite Je ki oore ofe ati aanu Re, Oluwa Ko ba le mi lori Oluwa, mo ke p'Oruko Re Je ki ojo aanu Re o, Baba Ko ro s'ori iseda mi Baba ooooo, eyi l'ebe o Baba Alaanu, Olugbebe, gbo ebe mi Oluwa o (Baba ooooo, eyi l'ebe o) Aye mi ko bu ola fun O ni mo n beere ...
Qdot - Atewo Lyrics
Motelimo sarifa tali Ma je k'aye bu mi pe camera mi o da Ma je k'aye fi mi sesin pe iwa mi o da Olorun Mose, omo Orimolade Tumolase Baba dami lohun; aye mi re, ba mi tunse Elohi o, iwo adaba; Elohi o, iwo adaba Adaba t'o wa ninu ogba, adaba mimo ni Adaba yi o wole (CHORUS) Meta meta latewo iye yi oh- Atewo eh eh iye ehhh, Atewo Meta meta latewo ...
Tope Alabi - Oluwa Otobi Lyrics
Oluwa o tobi o tobi o, o tobi ×2 kos'eni tale fi s'afiwe re o o tobi o, ko s'eda tale fi s'akawe re o o tobi o oluwa ×2 O tobi o, oluwa giga lorile ede gbogb gbigbega ni o pupopupo ni o o koja omi okun at'osa o ga po ajulo ose julo Oba Lori aye o tobi o eh agbani loko eru olominira ton deni lorun ofi titobi gba mi lowo ogun t'apa obi mi oka olugbeja mi to ba r'ogun lalai mu mi lo to segun ...
Lyrics Baba Lo Ran Mi Wa - Musixmatch - Song Lyrics and ...
eja lo da ke jeje baba lo ran mi wa ke emi wa lo gba te mi o gbo gbo abi nu eni oo eja lo da ke jeje abosi ti da yee ona ti jin ki shi ti daye ojõ tipe ija pelu ilara oo o ti daye ona ti jin oo jesu christi yes ni gba ton be laye yes ni shè lo ji oku dide yes o laju afoju yes omu won lara daa yes otun shìshè iyanu su gbon sibe sibe ko te won lo run rara yes won pu ro mo yes won shēê eke ...
Lara George - Run With You Ft. Lord of Ajasa Lyrics ...
Lord of ajasa: Igbekele omo eniyan, na mess up T'o ba b'olorun rin, o gbudo ni downfall Am still 'ere i thank God Maa tan generator ti nepa ba ti e mu'na lo Kaka k'o su mi a fun mi ni more inspiration So mi di role model ni waju awon new generation Oluwa o, tiyin ni mo se, iwo nikan (eh), lo'n gbe mi l'eke So mi o gbudo seke Authe ni baba ti mo ...
Yinka Ayefele - Next Level Praises Lyrics
Type song title, artist or lyrics. Top lyrics ... fun araye o wa so mi di ayan mo wa di ayan oloyimomo Oro mi di ijo oro mi dijo e wa bamiyo eba mi dupe ewabamiyo loni aye ye mi moroju rere olorun ogo ye o ose olorun ti o so mi di ayan oloyinmomo bi edumare ba le se se ti mo dide ri n gbogbo aye yin yio bami fi iyin fi ijo yin baba jake jado ...
Tope Alabi - Mo Sope Lyrics
Lyrics for Mo Sope by Tope Alabi. Mo sope okan mi bale Mo sope mo yin o logo.ooo Mo sope okan mi bale Ara tun mi, o Oluwa se...
Tope Alabi - Odara Ni Ife Lyrics
Type song title, artist or lyrics. Top lyrics Community ... e yin I bo ti ye K'orin tuntun s'Oluwa iwo okan mi E ma yo n'nu Oluwa eyin olododo Nitori iyin ye fun Oluwa E fi duru yin Oluwa t'ohun t'eelo orin K'orin naa s'oke kikan k'aye ko gbo o Nitori ile aye kun f'aanu Re E fi'ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda ...
Tope Alabi & Ty Bello - Oba mi De Lyrics
Lyrics for Oba mi De by Tope Alabi & Ty Bello. Called me out of the darkness He's calling you out of darkness Come into the light now He'... Type song title, artist or lyrics. ... Oba mi de Omo kiniun le sha layi ni Ebi a si ma pa won Omo kiniun le sha layi ni se Ebi a si ma pa won Awa to gbeke le oluwa Ki o sha layi ni oun to dara Oba mi n be ...
Pastor J. A. Adelakun - Amona Tete Mabo Lyrics
Lyrics for Amona Tete Mabo by Pastor J. A. Adelakun. ... ba de, l'aye yi to le toro o Igba ti Jesu ba de, l'aye yi to le dara Ikiri lojojumo, nise lofin gori ofin sibe sibe ara mi gbogbo, aye o fi be toro Ologun n be lode, aye n rojo kiri Oselu tun tun wo be o, igbe laraye nke oselu to koja lo, ejo laye n ro Ologun lo tun wobe o, Igbe laraye n ...
Yinka Ayefele - Living Testimony Lyrics
Lyrics for Living Testimony by Yinka Ayefele. Yo I'm a living testimony Oh oh oh Baba sekun mi dayo Oh oh oh Baba nomije mi nu Oh oh oh I'm a living testimony Oh oh oh Baba sekun mi dayo Oh oh oh Baba nomije mi nu Oh oh oh I'm a living testimony Oh oh oh my God sweet pass honey honey honey Oh oh oh See me before oh You go know wetin i dey talk Take me from oshodi down to ojota I dey ride okada ...
Tope Alabi - Oro Kan Soso Lyrics
Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Beeni mo wi Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi o Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Oro laseda fi d'aye at'orun Ohun gbogbo to wa ninu e, oro lo fi da B'aye at'orun ba yi pada, oro l'Olorun yio wa titi lai Tori oro ledidi ohun gbogbo Oro kan soso, o le tun se, oro kan soso Ohun ti a ti f'oro baje ninu aye mi ...
Tope Alabi - Iyin Ye O Lyrics
Oba to femi Kabiesi re o Iyin ye o Oba to femi Ogo ye o Kabiesi re o eh Ogba mi lowo iku Ore mi otito Ofi keke ogun aye mi jona Olu gbe ja mi ni Ko se ni to le se o; afi wo Kabiesi re o eh Mo juba mo fori ba le fo ba Iwo ni ologo julo Back to chorus O fo gbogbo ilekun ide aba wole si ogo mi Ojo gbogbo jankari wo Emi odi won teriba Okuta ti awon mole ko Wadi pataki igun aye Owo anu re to fi gba ...
DAVID OKE AGS - MO FE O LYRICS
The mercy of God is greater than what lips can tell (anu Oluwa, O koja ohun ti ete le royin o) If I walk with Jesus Christ, even if I stumble He'll lift me up (Ti mo ba ba Jesu rin, ti n ba subu a fa mi dide) In everything I do, Jesus, let me do your will (ninu ohun gbogbo ti mo ba n se Jesu, Je n le se'fe re) Oh Lord I need You (Oluwa mo fe o)
Tope Alabi - E Ma Ro'pe Lyrics
Lyrics for E Ma Ro'pe by Tope Alabi. Ema ro pe kole lowo mo Eni to jegun shi ma je eran Ore ma romipin eni to wakisa Shile woso igbayi tole o nbo wa de ro afaila ojo bojo ba laa ma la o Eniyan mi wonu olorun mi wokan ooo Oni e ro mi ki nse e ro yin rara Eda o laropin eni ta ro pe kole pa go le sebe ko kole alaruru Oju lope si I so ro oni o a la dun ola o O nse omo oloku be a ko ni sin sa mo o ...
Found 21 lyrics.

Recent lyrics

romanz


Close Ad