Yin oluwa okan mi by emmaohmygod lyrics

Yin oluwa okan mi by emmaohmygod lyrics

Get lyrics of Yin oluwa okan mi by emmaohmygod song you love. List contains Yin oluwa okan mi by emmaohmygod song lyrics of older one songs and hot new releases. Get known every word of your favorite song or start your own karaoke party tonight :-).


Tope Alabi - Odara Ni Ife Lyrics
E fi'ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye K'orin tuntun s'Oluwa iwo okan mi E ma yo n'nu Oluwa eyin olododo Nitori iyin ye fun Oluwa E fi duru yin Oluwa t'ohun t'eelo orin K'orin naa s'oke kikan k'aye ko gbo o Nitori ile aye kun f'aanu Re E fi'ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye Emi t'a ...
Seun&Wumi Akinwole - Emi O Kokiki Re Oluwa Lyrics
Emi yio k'okiki re Oluwa Iwo ni o da mi nide Iwo ni koje ki ota yomi Ogo ni f'oruko re Iyin ola, ogo ni fun o Agbara ati'pa je tire Egberun ahonko to yin o A wole a juba re. Oluwa mi emu kigbe pe o Iwo si my mi larada O yo okan mi kuro ninu 'sa oku O si pami mo laaye Korin s'oluwa eyin serafu Kesi dupe 'wa mimo re Ibinu re kiipe ju seju kan Iye ...
Tope Alabi - Mo Sope Lyrics
Mo sope okan mi bale Mo sope mo yin o logo.ooo Mo sope okan mi bale Ara tun mi, o Oluwa seun (Beats) Ara tun mi, okan mi bale Mo dupe gbede lo ro mi o Tele ri osuka mi ga Eru mi po, mo rina titi Lai de'bute Ile n su, Ile n mo, Ajo mi o yena Back to chorus Mo dupe, o f'ara tun mi gbede Oorun aye tani, af'ara eni kona E da aye feyin sini, pada wa soni loko Olorun ni o je, koga aye gbaso lorun mi ...
TOYIN ALO - HALLELUYAH LYRICS
Toyin Alo - Halleluyah Lyrics. okan mi yin oluwa halleluyah eni ba more jesu ko bami gbega okan mi yin oluwa halleluyah eni ba more jesu ko ba mi gbega eni ba more jesu ko. Lyrics. Popular Song Lyrics. Billboard Hot 100. Upcoming Lyrics. Recently Added. Top Lyrics of 2011. Top Lyrics of 2010.
Lyrics Search halleluyah
okan mi yin oluwa halleluyah eni ba more jesu ko bami gbega okan mi yin oluwa halleluyah eni ba more jesu ko ba mi gbega eni ba more jesu ko ba mi gbega eni ba more jesu ko ba mi gbega okan mi yin olu. Halleluyah Lyrics. by Toyin Alo on album Toyin Alo.
Tope Alabi - Mo Mope Mi Wa Lyrics
Oba to ku nitori mi, oba taa pa nitori ese mi, Oba taa kan nitori mi. Mo mope mi wa fun o Ada lebi iku, kemi le gba idalare Ano ni pasan, kemi maba jiya Oti kikan tomu, kinmaba jekoro ni Atuto si lara, kemi le deni aponle Ikoro irora toje nitori temi ni Oba toku nitori mi, oba taapa nitori ese mi Oba taa kan nitori mi, mo mope mi wa fun o La layi jebi ese, asi da lébi èshè Isho owo ati ese ...
Kunle Kenny feat. Anuu - Ose Baba Lyrics
Looking at my life i know you brought me through the reason have come this far is just because of you i stood it to ask my self why you love me so ife re o ga ju Thats why i sing you this song Baba ose ose fun ore re lo ri mi emi koni gbagbe re o ma ma se o baba(2) Alagbawi eda, Asoro ma ye hun With everything, every breath that i take i give you the praise You brought me out of the muddy clay ...
Sola Allyson Obaniyi - Adura Ololufe Lyrics
Owo o ni wan n'ile wa Owo Olorun nbe lara wa Owo Oluwa nba wa lo Imole a ma tan si Ope ti mo nda l'ojojumo ree ore okan t'eledua fun mi maa gbo Modupe mo yin'le f'olu to gbe mi pade alaanu Mosope mi o kuta l'oju oja ife, eleda lo ba mi se Alabarin t'eledua yan fun o gangan ni moje Alabase t'olorun fifun mi gangan ni iwo je Ajose wa a maa mayo ...
ANGéLIQUE KIDJO - OKAN BALè LYRICS
Okan balè o, okan balè o Okan balè o, okan balè o Eminin kan ko lo wa I'ayé é Omon dada I'émin, mon nin èbi kpikpo Mon mon gbogbo èbi témi I'aué é Irinsi dada ni, témin ègbo o Mo mon m'kpé èfè ran mio Edjè kin ma doukpè foun yin Ifè yin foun mi I'ayo Monfè ki ayé témin ko da
Sola Allyson Obaniyi - Iwo Lo Ye Lyrics
Hallelujah Ogo ni fun Baba A fijo filu yin Olorun wa Alaaye ni yoo yin O bo ti ye Hallelujah Ogo Oluwa ooo Eh eh Oluwa ooo Eh eh Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa Oluwa Oba to mo Dafidi fi isori E so wa Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa eeeh Oluwa Oba to ni ike ige fi isori E so wa Ope ye O ooo eh Ope Eni to joko lori ite ogo fooko ...
Found 10 lyrics.

Recent lyrics

kenta
nkwe
bedona