Yin oluwa olododo lyrics

Get lyrics of Yin oluwa olododo song you love. List contains Yin oluwa olododo song lyrics of older one songs and hot new releases. Get known every word of your favorite song or start your own karaoke party tonight :-).


Get hot Yin Oluwa Olododo lyrics at Lyrics.camp!
Tope Alabi - Odara Ni Ife Lyrics
E fi'ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye K'orin tuntun s'Oluwa iwo okan mi E ma yo n'nu Oluwa eyin olododo Nitori iyin ye fun Oluwa E fi duru yin Oluwa t'ohun t'eelo orin K'orin naa s'oke kikan k'aye ko gbo o Nitori ile aye kun f'aanu Re E fi'ba fun Un, e yin I o Awon angeli, won n yi ite Re ka Gbogbo eda eniyan, e yin I bo ti ye Emi t'a ...
Bukola Anney feat. Esther Adegbayo - Yoruba Praise and ...
Ti Oluwa ni ile ati ekun re, aye ati awon ti otedo sinu re, nitoripe, oti fi ile sole sori okun, ati sori isan omi. e gbe ori yin soke, eyin enu ona, ki asi gbeyin soke, eyin ilekun ayeraye, ilekun ayeraye, ilekun ayeraye. koba ogo, koba ogo, Oluwa ti ole, Oluwa to ni agbara, ologo didan, eleru niyin, apa nla to so ile aye ro, ko ni nira fun mi ...
Tope Alabi - Oruko Oluwa Lyrics
Lyrics for Oruko Oluwa by Tope Alabi. Maa yin O, Olorun t'O dara, t'O n s'ohun gbogbo fun mi o Emi o yin O, imole to n f'ona han... Type song title, artist or lyrics. Top ... oruko Re ko le pin Titi aye, oruko Re ko le pin Alagbara, Olododo, Atobiju lOluwa Alaanu o lOluwa, oruko Re n gba ni la Oruko Re n gbe ni ro, oruko Re n so ni d'oloro ...
Found 3 lyrics.

Recent lyrics

arjati
mr boo
vamo