Slow down on aaaa... manya diet
Igbe eshin ni won pe ni loud abi
Ibi ti o fe gba yen, o ma ja ticket omo iya mi,
Wo n lo n feel shit mi ni street,
Ma wo bi won she sare mu,
Nigba ti won wa ri mi pelu wizzy nkan, gbogbo wan wa manye wu,
(Exclusive) Black panther,
Affordable for the street,
Alaye, eja yiyan lawa n ta,
Alaye, mo ti san owo omo onile jo, ki n to yo foundation,
Omo ase ni wo n pe ni sapon,
Won lo n feel shit mi ni street,
Ma wo bi won she sare mu,
Nigba ti won wa ri mi pelu wizzy nkan,
(Exclusive) Black panther,
Affordable for the street,
Won ti bo si ori third mainland brigde,
Ti n ba je mourinho, o ma bench e,
Otunba lamba, sho le last mi?
At all at all ni won pe wunre,
Oga ade ki o to lo, o ma mu nkan le o,
Won lo n feel shit mi ni street,
Ma wo bi won she sare mu,
Nigba ti won wa ri mi pelu wizzy nkan,
(Exclusive) Black panther,
Affordable for the street,
Gbogbo Oju e to n le yen,
Ti o ba ti mo pe o lowo VIP ko fi aye le,
Tiz slimcase in the building,