Are you an artist? Make the most of your lyrics with Musixmatch Pro!
Add translation
Share
Verified by Curator
4 contributions
almost 4 years ago
Translations

Lyrics of Next Level Praises by Yinka Ayefele

Iyin ati ope loye fun baba
Iyin ati ope fun messiah
Oba ti o pa wa mo ninu ewu
Iyin ati ope fun Jehovah
Bi mo ba lawo ti o po to one thousand
Ko ti e le to lati yin oooo
Agaba igbega ti mo wa yii ni next level
Iyin ati ope fun Jah Jehovah
Iyin, ogo ye oo
Modupe o baba mi ogo ye o
Emi ti won ko bata fi ra atupa lo jo si
Mo wa di eni ajitona fun araye o wa
So mi di ayan mo wa di ayan oloyimomo
Oro mi di ijo
Oro mi dijo e wa bamiyo eba mi dupe
Ewabamiyo loni aye ye mi
Moroju rere olorun ogo ye o ose olorun ti o so mi di ayan oloyinmomo
Bi edumare ba le se se ti mo dide ri n gbogbo aye yin yio bami fi
Iyin fi ijo yin baba jake jado agbaye okiki a kan je ko sese daabobo
Mi o awon toku to n ba binu je ki inu won ro,
Je ki inu won ro ki a le fi idunnu jaye pe bi won ba wa ko wipe awon
O gba wa se won mose fi won se sample iya ki won le mo pe iwo lo Oba
Bi mo ba se re lowo,
Ayefele bi mo ba gbo ilu bi mo ba ri ilu inu mi a dun
Ara mi a ya gaga ose olorun ti o so mi di ayan oloyinmomo
Ba se lu lu yi bi e se n jo iku o ni
Pawa o aarun o ni se yin o ka jo ma se pepepe
Ayefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomo
Hypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo na
Pa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupo
Hypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo 2ce
Ojo ti o ro ti o kun ikoko ni agbala ojo oun lo ro sinu apere ti ko
De kun so ikoko wa yo wipe apere o le mu ojo dani e bami so fun ikoko
Ki ikoko mama yo mo asiko n bo wa fun apere bi ojo ba da tan apere n
Bo wa ko ore oko bi ojo ba ti da igba eda asiko eda wa lowo baba
Oke pa ironu ti ore asiko re bo wa
De pa ironu ti o ya bere mo le si jo
Ayefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomo
Hypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo na
Pa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupo
Hypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo 2ce
Ti o ba rii se ma se pe padii e lo le because onitiri ola tun le
Saalaye be e mo ko si owo loni owo n bo bi o dola ko si ola loni ola
N bo bo dola agan mama beru mo omo n bo wa asiko eda igba eda wa lowo
Baba oke then ironu pupo hypertension ma de
Lo tun fa wa pa ironu oya bere mo le si ijo
Ayefele tunti de alujo tun ti de o ya wa ka jojo ilu oloyinmomo
Hypertension o le raye bi ilu ba n dun alujo po ninu ilu yii e mo na
Pa ronu ti ore beere wa ka jo jo ironu pupo
Hypertension ma lo n fa wa beere oya beere oya beere wa ka jo jo 2ce
Be emi ko olorun mi o ori mo mu waye ori owo ni ori mo.
Mu wa ye oriola ni agbon ti o ni omi ninu ko si eni ti o mo idi re
Writer(s): Olayinka Joel Ayefele

Contribute

To-do

Structure Tag
Identify the song's sections

Completed

Lyrics
Verified by Curator
Performers Tag
Identify who's singing what

Credits

This song has no credits yet

Contributions

Last edit almost 4 years ago
Are you an artist? Distribute your lyrics!
Take full control of your lyrics. Curate, sync, and distribute your lyrics on Spotify, Apple Music, and more.
Explore Musixmatch Pro